LG 15FC2RB Manuel Du Propriétaire page 31

Masquer les pouces Voir aussi pour 15FC2RB:
Table des Matières

Publicité

Les langues disponibles

Les langues disponibles

SSM (Ipo Atari Ohun)
O le yan eto ohun rẹ ti o fẹ; Gbalaja, Orin, Aworan
ti nrin, Ere-idije ati Olumulo.
Tẹ bọtini MENU lera lera lati pada si ipo akọkọ TV
yii.
Ohun
,
,
Flat
Music
Movie
pese lori ẹrọ yii fun ohun to gbamuse lati ọdọ awọn
to se ẹrọ yii ko sẹ e yi pada.
Yiyan ohun turbo
Ti eyi ba wa ni titan o ma n jẹ ki ohun ja fere ju
boti yẹ lọ.
Didari ohun
O le ṣatunto iwọntunwọnsi, Tirebulu, Baassi AVL
(Ipele Iwọn- didun Aifọwọyi, AVL nṣe itọju ipele
iwọn didun to ṣe deede, paapaa ti o ba yi awọn eto
pada. Ohun Ayipada nṣẹda gbogbo ohun ayika bi
ni apejọ ere-orin.
X-WAVE (Ohun ti o lokun) (iyan)
O si tun le tẹti si ohun yii lori ero amititi FM.
Akiyesi :
a. Ti o ba ri wipe ohun yiio ja fefe, nawọ gan aye
miran lori afẹfẹ.
b. Lati ri esi ti o dan mọran, mase je ko TV ati FM
jina sira ju 5m (16.4ft) lọ.
c. Ni agbegbe miran, ijade FM le ma ja fafa, fun
apẹrẹ eyi to sun mo opo iro ohun.
d. Agbara atigba ohun lori afẹfẹ le da lori asọrọ
magbesi (FM radio).
Yiyan ohun si ita
Ninu isẹ AV, o le nawọ gan ohun ita igbohunsoke
ti apa otun ati apa osi.
*
Tẹ bọtini I/II/
lera lera lati nawọ gan jijade ohun.
: Ohun to ba wa lati L yio bọsi igbohunsoke ti
L+R
apa osi, ohun to ba wa lati R yio bo si igbo-
hunsoke ti apa ọtun.
: Ohun to ba jẹyọ lati L yio lo si igbohunsoke
L+L
apa ọtun ati osi bakan naa.
: Ohun to ba wa lati R yio lọ si igbohunsoke
R+R
apa ọtun ati osi bakan naa.
Didari ohun
Gbigba Stereo/ Meji
Ti eto kan ba ti wa ni idawọle, iroyin ohun fun
sitesọn jẹyọ nigbati nọmiba eto ati sitesọn ba di
awati.
Wa lori afefe
Ẹlẹyo kan
Stereo
ati
ti wa ni
Sports
Oni meji
Yiyan ohun eleyokan
O le tẹ bọtini I/II/
ba le bọ si afẹfẹ dara dara.Niti ẹlẹyọkan nigbigba
ohun yi yi gun rege. Lati pada si stereo, tẹ bọtini
*
I/II/
Yiyan ede fun ede oni meji
Ti eto kan ba wa pẹlu ede meji (ede meji), o le
pada si
botini I/II/
DUAL I
DUAL II
ẹrọ igbohunsoke.
DUAL I + II
kan kan.
NICAM reception (iyan)
Ti ẹrọ ẹ ba wa pẹlu eroja NICAM yii, nigba
naa ni o le jẹ anfani NICAM (Near Instantenous
Companding Audio Multiplex) yii.
O le nawọ gan jijade ohun nipa titẹ bọtini I/II/
lera.
1. Nigbati ọ ba gba NICAM, o le nawọ gan
NICAM MONO
2. Ti stereo NICAM ba di riri, o le nawọ gan
NICAM STEREO
ba ja fefe lori afẹfẹ, o le pada si FM mono.
3. Ti NICAM dual ba di riri, o le nawọ gan
NICAM DUAL I
NICAM DUAL I + II
mono bajẹ itẹwọgba
iran.
Ijẹyọ loju iran
MONO
STEREO
DUAL I
*
lee meji ni wọn gba ti stereo o
lee meji lẹẹkan si.
,
tabi
DUAL I
DUAL II
DUAL I+II
*
lera leraọ.
ma n dari ijade eto ede si ẹrọ igbohunsoke.
ma n dari apakeji ijade eto ede si awọn
ma n dari ede ọtọ si ẹrọ igbohunsoke
tabi FM MONO.
tabi FM MONO. Ti stereo o
,
NICAM DUAL II
tabi
MONO
nipa tite
*
lera
tabi
. Ti FM
MONO
yio juyọ loju
7

Publicité

Chapitres

Table des Matières
loading

Table des Matières